Págà! A kò rí oun tó jọ "Yọrí"
Ǹjẹ́ o fẹ́ràn láti fi orúkọ kún àwọn orúkọ wa?
Jọ̀ọ́ lọ sí abala ibi tí a ti ń forúkọ sílẹ̀.Wò níbí àwọn orúkọ tó lè jọ ara wọn
Adéyọrí
Meaning: The crown triumphed.
Aláṣeyọrí
Meaning: The successful one.
Ayòrindé
Meaning: Joy walks in.
Ayọ̀rìndélémi
Meaning: Joy walked to my house.
Ayọ̀rìnmóyè
Meaning: Joy walks with honour.
Ọláyọrí
Meaning: Wealth triumphed.
Olúyọrí
Meaning: The leader succeeds. God succeeds.
Omiyọrí
Meaning: Water triumphs.
Tèmiyọrí
Meaning: Mine is successful.