Págà! A kò rí oun tó jọ Yẹni
Ǹjẹ́ o fẹ́ràn láti fi orúkọ kún àwọn orúkọ wa? Jọ̀ọ́ lọ sí abala ibi tí a ti ń forúkọ sílẹ̀.

Wò níbí àwọn orúkọ tó lè jọ ara wọn


Adékóyẹni

Brief Meaning: One who arrives bringing honour.


Aiyénítajú

Brief Meaning: There is no hurry in life: "Aiye ò ní ìkánjú"


Akéréyẹni

Brief Meaning: One who is honourable, in spite of their small stature.


Awóyẹni

Brief Meaning: The priesthood is befitting of one.


Ayénígbà

Brief Meaning: Life is time-bound; Life is seasonal.


Ayénípẹ̀kun

Brief Meaning: The world has no end.


Ayẹni

Brief Meaning: He or that which is deserving or befitting.


Ayẹnibíowó

Brief Meaning: That which befits a person like money.


Iyeniwúrà

Brief Meaning: The mother is gold.


Kùtùọláyẹni

Brief Meaning: The early arrival of honor/wealth befits a person.


Láyẹni

Brief Meaning: Wealth befits one.


Mọ́yẹni

Brief Meaning: The child is worthy of one.


Oyèníran

Brief Meaning: Chieftaincy is generational.


Oyèníkẹ́

Brief Meaning: Chieftaincy has care.


Oyèníyì

Brief Meaning: Honor has dignity.


Oyèníún

Brief Meaning: Honor contains celebration.


Ọláyeni

Brief Meaning: Wealth befits one.


Ọmọ́yẹni

Brief Meaning: Child befits one.


Ayégbajẹ́jẹ́

Brief Meaning: Life is best enjoyed slowly/carefully.


Okèníyì

Brief Meaning: The hills have value.


Olúníyọ̀

Brief Meaning: The leader has sweetness.