Págà! A kò rí oun tó jọ Yalé
Ǹjẹ́ o fẹ́ràn láti fi orúkọ kún àwọn orúkọ wa? Jọ̀ọ́ lọ sí abala ibi tí a ti ń forúkọ sílẹ̀.

Wò níbí àwọn orúkọ tó lè jọ ara wọn


Adéyalé

Brief Meaning: The crown has visited our home.


Ajéyalémi

Brief Meaning: Business/Industry came to my house.


Awóyalé

Brief Meaning: The fraternity (e.g. of Ifá) came by the house (reincarnated).


Máyaléèké

Brief Meaning: Don't visit the house of the dishonest person.


Odùyalé

Brief Meaning: Ifá has visited our house.


Omíyalé

Brief Meaning: The river god(dess) stopped by the house. A Yemọja priestess has reincarnated.


Owóyalé

Brief Meaning: Money detoured to (my) home.


Ògúnyalé

Brief Meaning: Ògún came back home.


Ọdẹ́yalé

Brief Meaning: The hunter detoured into the home.


Ọnàyalé

Brief Meaning: (The descendant of) the ornamental worker detoured into (my) home.


Ọyalékè

Brief Meaning: Ọya triumphs.