Págà! A kò rí oun tó jọ Wọ̀lú
Ǹjẹ́ o fẹ́ràn láti fi orúkọ kún àwọn orúkọ wa?
Jọ̀ọ́ lọ sí abala ibi tí a ti ń forúkọ sílẹ̀.
Wò níbí àwọn orúkọ tó lè jọ ara wọn
Adékọ́láwọ̀lú
Brief Meaning: The crown has brought honor into the town.
Adéwọ̀lú
Brief Meaning: Royalty enters the town.
Awólúsì
Brief Meaning: The oracle has fame.
Awọ̀lúmátẹ́
Brief Meaning: One who is never disgraced on entering a (new) town/place.
Ògúnwọ̀lú
Brief Meaning: Ògún has entered the town.