Págà! A kò rí oun tó jọ "Wọyè"
Ǹjẹ́ o fẹ́ràn láti fi orúkọ kún àwọn orúkọ wa?
Jọ̀ọ́ lọ sí abala ibi tí a ti ń forúkọ sílẹ̀.Wò níbí àwọn orúkọ tó lè jọ ara wọn
Adélúwọyè
Meaning: The crown has mixed and entered chieftaincy.
Adéwọyè
Meaning: The crown has entered the chieftaincy.
Akínwọyè
Meaning: Valor enters honour.
Arówóyẹlé
Meaning: One who finds money to befit the home.
Awóyẹlé
Meaning: The oracle belongs in the house.
Awóyẹmí
Meaning: The oracle befits me.
Awóyẹni
Meaning: The priesthood is befitting of one.
Awóyẹra
Meaning: The initiated one(s) has/have left.
Àyánwọyè
Meaning: The drummer has entered honor (chieftaincy title).
Ìbíwọyè
Meaning: Good birth entered into chieftaincy.
Odùwọyè
Meaning: The Ifa corpus has entered honour (chieftaincy).
Ojúwòyè
Meaning: [meaning unknown]
Ọláwọyè
Meaning: Wealth enters the title.
Olówóyè
Meaning: The rich survives.
Olówóyẹyè
Meaning: The rich man is deserving of honour.
Olúfawoyè
Meaning: The head survives with the oracle. [verification needed]
Owóyẹlé
Meaning: Money befits the house.
Owóyẹmí
Meaning: 1. I deserve to be wealthy. 2. Wealth fits/suits me.
Ọyáwọyè
Meaning: The goddess Ọya has entered honour.
Onígbìndé
Meaning: The bearer of the Igbin has come.