Págà! A kò rí oun tó jọ "Wuyì"
Ǹjẹ́ o fẹ́ràn láti fi orúkọ kún àwọn orúkọ wa?
Jọ̀ọ́ lọ sí abala ibi tí a ti ń forúkọ sílẹ̀.Wò níbí àwọn orúkọ tó lè jọ ara wọn
Adéwuyì
Meaning: The crown is valuable.
Ifáwuyi
Meaning: Ifa is valuable.
Láwuyì
Meaning: Wealth is valuable.
Ògúnwuyì
Meaning: Ògún is prestigious. Ògún is admirable.
Ọ̀jẹ́wuyì
Meaning: The masquerade is honourable.
Òkéwuyì
Meaning: The hills are valuable.
Oláwuyì
Meaning: Honour is valuable
Olúwuyì
Meaning: 1. Prominence is valuable, admirable. 2. God is valuable, admirable.
Ọláfuyì
Meaning: (Our) wealth is honourable.
Akínṣuyì
Meaning: Valor is notable/valuable/honourable.
Ifásuyì
Meaning: Ifá is notable.
Ṣàngóbuyì
Meaning: Ṣàngó is prestigious.
Olúsuyì
Meaning: 1. God makes a valuable thing 2. God is valuable.
Shófuyì
Meaning: The sorcerer is honourable.
Ṣófuyì
Meaning: The fertility god is honourable.