Tóyìn
Sísọ síta
Ìtumọọ Tóyìn
Worthy of praise.
Àwọn àlàyé mìíràn
A common short form of "Olúwatóyìn": God/ the almighty is worthy of praise.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
tó-yìn
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
tó - worthy of, sufficient foryìn - praise
Agbègbè
                        Ó pọ̀ ní:
                            
GENERAL                    
Àwọn Ènìyàn Gbajúọ̀
- TY Bello (singer 
- songwriter 
- photographer and philanthropist) Tóyìn Aimakhu (actress 
- filmmaker 
- director and producer) 
