Págà! A kò rí oun tó jọ Túyì
Ǹjẹ́ o fẹ́ràn láti fi orúkọ kún àwọn orúkọ wa?
Jọ̀ọ́ lọ sí abala ibi tí a ti ń forúkọ sílẹ̀.
Wò níbí àwọn orúkọ tó lè jọ ara wọn
Adétúyì
Brief Meaning: The crown is worth lots of value.
Aládétúyì
Brief Meaning: The owner of the crown is worthy of honor.
Àgbétúyì
Brief Meaning: Àgbé is worth of honor.
Fátúyì
Brief Meaning: Ifá is honourable. Ifá is worth honouring.
Ìbítúyì
Brief Meaning: (Good) birth is worth some value.
Ìjátúyì
Brief Meaning: Ìja is worthy of honor.
Olókètúyì
Brief Meaning: The people of the hill are honourable.
Olúwatúyì
Brief Meaning: The lord is worth plenty. [verification needed]
Ògúntúyì
Brief Meaning: Ògún is worthy of honor.
Ògúntúyìn
Brief Meaning: Ògún is worthy of praise.
Ọ̀gbẹ̀sẹ́túyì
Brief Meaning: Ọ̀gbẹ̀sẹ̀ is worthy of honor.
Ọ̀sanyíntúyì
Brief Meaning: Ọ̀sanyìn is worthy of honor.
Ẹlẹ́fọ̀ntúyì
Brief Meaning: The Ẹlẹ́fọ̀n deity is worthy of honor.
Ọlọ́fíntúyì
Brief Meaning: Ọlọ́fin is worthy of honor.
Ọlọ́batúyì
Brief Meaning: One with royalty (in his blood) is highly respected.
Ọrẹ̀túyì
Brief Meaning: The Ọrẹ̀ deity is honourable.
Ọ̀ṣúntúyì
Brief Meaning: Ọ̀ṣun is worth honouring.
Àgbédèyí
Brief Meaning: Àgbé became this.
Ẹlẹ́fọ̀ntádé
Brief Meaning: Ẹlẹ́fọ̀n deity is worthy of a crown.
Aṣẹ̀fọ̀n
Brief Meaning: One who worships the Ẹlẹ́fọ̀n (Ẹ̀fọ̀n) deity.