Págà! A kò rí oun tó jọ Túdé
Ǹjẹ́ o fẹ́ràn láti fi orúkọ kún àwọn orúkọ wa?
Jọ̀ọ́ lọ sí abala ibi tí a ti ń forúkọ sílẹ̀.
Wò níbí àwọn orúkọ tó lè jọ ara wọn
Òtúdẹ́kọ́
Brief Meaning: The elder has become (a source of) knowledge.
Ọ̀jẹ́túdé
Brief Meaning: A variant of Ọ̀jẹ́túndé, the Egúngún (masquerade) worshipper has returned again.
Adélákin
Brief Meaning: The crown has fortitude.
Fèyísọpẹ́
Brief Meaning: Use this for gratitude.
Ṣodiípọ̀
Brief Meaning: The sorcerer has become a multitude.
Títílọpẹ́
Brief Meaning: (Our) Gratitude is forever.
Ajísegírí
Brief Meaning: One who has a quick attitude to work.
Ajíṣọpẹ́
Brief Meaning: One who renders offerings of gratitude daily.
Ọpẹ́midọ̀tun
Brief Meaning: My gratitude has been renewed.
Ọpẹ́olúwa
Brief Meaning: 1. The grace of God. 2. Gratitude to God. 3. God's gratitude
Gbanejọkẹ́
Brief Meaning: Two hundred people gathered to care for him/her. A multitude cares for him/her.
Kìkìọpẹ́
Brief Meaning: Just gratitude (is what is deserving of God).
Adékáyọ̀wá
Brief Meaning: Royalty brought joy in multitudes.
Ṣódípọ̀
Brief Meaning: A variant of Ṣódiípọ̀, The sorcerer has become a multitude.
Ẹ̀ríọpẹ́mi
Brief Meaning: The testimony of my gratitude.
Ọyátọ́pẹ́
Brief Meaning: Ọya is worthy of gratitude.
Elúyẹra
Brief Meaning: The Elú person has left, departed.
Adùnbárìn
Brief Meaning: One sweet to walk with.