Págà! A kò rí oun tó jọ Tiwa
Ǹjẹ́ o fẹ́ràn láti fi orúkọ kún àwọn orúkọ wa?
Jọ̀ọ́ lọ sí abala ibi tí a ti ń forúkọ sílẹ̀.
Wò níbí àwọn orúkọ tó lè jọ ara wọn
Tiwadọlá
Brief Meaning: Ours become success.
Tiwaladé
Brief Meaning: Royalty is ours.
Tiwaladéolúwa
Brief Meaning: Ours is the crown of the lord.
Tiwalayọ̀
Brief Meaning: Ours is joy.
Tiwalolú
Brief Meaning: Prominence is ours. God is ours.
Tiwalolúwa
Brief Meaning: God is ours.
Tiwaloreọ̀fẹ́olúwa
Brief Meaning: The grace of God is ours.
Tiwalọlá
Brief Meaning: Ours is wealth.
Tiwanioreọ̀fẹ́olúwa
Brief Meaning: The grace of God is ours.
Tiwaniyì
Brief Meaning: Honour is ours.
Tiwanìfẹ́
Brief Meaning: Ours is love.
Tiwatádé
Brief Meaning: Ours is worth being crowned for.
Tiwádayọ̀
Brief Meaning: Our affairs have become joyful
Tiwátáyọ̀
Brief Meaning: Ours is worth being joyful for.
Tiwátọ́pẹ́
Brief Meaning: We have reason(s) to be thankful.
Tiwáyọ̀
Brief Meaning: Ours rejoices.