Págà! A kò rí oun tó jọ "Ròkun"
Ǹjẹ́ o fẹ́ràn láti fi orúkọ kún àwọn orúkọ wa?
Jọ̀ọ́ lọ sí abala ibi tí a ti ń forúkọ sílẹ̀.Wò níbí àwọn orúkọ tó lè jọ ara wọn
Fájẹ́mirókun
Meaning: Ifá gives me vitality.
Ifájẹ́mirókun
Meaning: Ifá allowed me to see the ocean.
Oníyìròkun
Meaning: The honorable person has went to the ocean.
Oròkúnbí
Meaning: Orò has been added to the family lineage.
Oròkúnlé
Meaning: Orò has filled the house.
Oyèròkun
Meaning: Honor has journeyed to the ocean.
Yéròkun
Meaning: Mother went to the ocean.