Págà! A kò rí oun tó jọ "Rìnọ́lá"
Ǹjẹ́ o fẹ́ràn láti fi orúkọ kún àwọn orúkọ wa?
Jọ̀ọ́ lọ sí abala ibi tí a ti ń forúkọ sílẹ̀.Wò níbí àwọn orúkọ tó lè jọ ara wọn
Àárínọlá
Meaning: Center of honor.
Adérìnọ́lá
Meaning: The crown walks in wealth.
Akínrìnọ́lá
Meaning: Valor walks into wealth.
Àrínọlá
Meaning: (Born) in the midst of wealth.
Ẹ̀rínọlá
Meaning: The joy of success/nobility, etc.
Ìbírìnọ́lá
Meaning: (Good) birth/pedigree walks into success.
Kọrinọlá
Meaning: Sing a song of success.
Ọ̀̀jẹ̀rìnọ́lá
Meaning: The masquerade walks into wealth.
Ọmọ́rìnọ́lá
Meaning: The child walks into success.
Ṣórìnọ́lá
Meaning: The sorcerer walks into success.
Adérìnlọ́lá
Meaning: The crown walks to have wealth/success.