Págà! A kò rí oun tó jọ "Pàdé"
Ǹjẹ́ o fẹ́ràn láti fi orúkọ kún àwọn orúkọ wa?
Jọ̀ọ́ lọ sí abala ibi tí a ti ń forúkọ sílẹ̀.Wò níbí àwọn orúkọ tó lè jọ ara wọn
Akínpàdé
Meaning: The valiant ones meet.
Bájépàdé
Meaning: Meet with business success.
Ìpàdéọlá
Meaning: The meeting of wealth.
Lápàdé
Meaning: Weath reunites.
Mápadérun
Meaning: Do not destroy royalty.
Ọlápàdé
Meaning: Nobility (from two houses) meets.
Ọlọ́pàdé
Meaning: The devotees of the Ọ̀pá deity have arrived.
Ọ̀pádèjì
Meaning: The ọ̀pá has become two.
Ọ̀pádèrè
Meaning: Òrìṣàoko has become an idol/figurine (to be worshipped).
Ọlọ́pàádé
Meaning: The Ọpa (re|re) devotee has come.