Págà! A kò rí oun tó jọ "Orósùn"
Ǹjẹ́ o fẹ́ràn láti fi orúkọ kún àwọn orúkọ wa?
Jọ̀ọ́ lọ sí abala ibi tí a ti ń forúkọ sílẹ̀.Wò níbí àwọn orúkọ tó lè jọ ara wọn
Orósúndafọ̀sí
Meaning: The goddess Orósùn has become one who we can speak to.
Orósúndákintẹ́
Meaning: The goddess Orósùn did not allow the warrior to be disgraced.
Orósúndélé
Meaning: The goddess Orósùn has arrived to the house.
Orósùnèjẹ̀bi
Meaning: The goddess Orósùn is not to blame.
Orósúngùnlékà
Meaning: The goddess Orósùn does not oversee wickedness.
Orósúnkẹ̀hìn
Meaning: Orósùn did not turn her back.
Orósúnnẹ́gàn
Meaning: Orósùn does not disparage or criticize; The worship of Orósùn is not shameful.
Orósúnṣuyì
Meaning: The goddess Orósùn has brought forth honor.