Oròdìran
Sísọ síta
Ìtumọọ Oròdìran
The worship of Orò has become generational.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
orò-di-ìran
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
orò - deity of bullroarers, peace, justice, and securitydi - become
ìran - generation(s), genealogy, lineage
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
OGUN