Olúwajẹ́kínyọ̀

Sísọ síta



Ìtumọọ Olúwajẹ́kínyọ̀

God allowed me to rejoice.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

olúwa-jẹ́-kí-n-yọ̀



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

olúwa - lord, God
jẹ́ - permit, to exist, to be effective
- that; may
n - me
yọ̀ - rejoice


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
OYO



Irúurú

Jẹ́kínyọ̀