Olúwadùnmínínú

Sísọ síta



Ìtumọọ Olúwadùnmínínú

The Lord has gladdened my heart.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

olúwa-dùn-mí-ní-inú



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

olúwa - lord, God
dùn - sweeten, gladden
mí - me
ní - in
inú - inside, heart, soul


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Dùnmínínú