Olúwáfèyídárà
Sísọ síta
Ìtumọọ Olúwáfèyídárà
God performed wonder with this one.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
olúwa-fi-èyí-dárà
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
olúwa - lord, Godfi - use
èyí - this (one)
dárà - make wonder
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
IBADAN