Olúwaòdójútìmí
Sísọ síta
Ìtumọọ Olúwaòdójútìmí
God did not let me down.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
olúwa-ò-dójútì-mí
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
olúwa - God, Lordò - did not
dójútì - disgrace, let down
mí - me
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
ILESHA