Olúwáfọládáràfúnmi

Sísọ síta



Ìtumọọ Olúwáfọládáràfúnmi

God used honor/wealth to do wonders for me.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

olúwá-fi-ọlá-dá-àrà-fún-mi



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

olúwá - Lord, God
fi - put
ọlá - wealth, success, nobility
- to create
àrà - wonders
fún - for
mi - mine


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL