Olúrẹwà

Sísọ síta



Ìtumọọ Olúrẹwà

The prominent one is beautiful.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

olú-rẹwà



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

olú - prominent one, God (Olúwa)
rẹwà - be beautiful


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Olúwarẹwà