Odùṣẹ̀ṣọ́
Sísọ síta
Ìtumọọ Odùṣẹ̀ṣọ́
Ifá has created an adornment.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
odù-ṣe-ẹ̀ṣọ́
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
odù - Ifá corpus/text; Ifá divination; message of Ifáṣe - make, create (something good)
ẹ̀ṣọ́ - guard (ọ̀ṣọ́/ẹ̀ṣọ́), protector, warrior, adornment
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
IJEBU