Òkédáìró

Sísọ síta



Ìtumọọ Òkédáìró

The deity of the hill spared this one.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

òkè-dá-èyí-ró



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

okè - the (deity of the) hill
dá...ró - spare
èyí - this (one)


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
OYO



Irúurú

Dáìró