Ògúnǹdójútìmí

Sísọ síta



Ìtumọọ Ògúnǹdójútìmí

Ògún (my protector deity) has never let me down.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ògún-ǹ-dójútì-mí



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ògún - Ògún, god of iron
- does not
dójútì - disgrace, let down
mí - me


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
ONDO
OWO



Irúurú

Ògúndójútìmí

Dójútìmí