Págà! A kò rí oun tó jọ "Moní"
Ǹjẹ́ o fẹ́ràn láti fi orúkọ kún àwọn orúkọ wa?
Jọ̀ọ́ lọ sí abala ibi tí a ti ń forúkọ sílẹ̀.Wò níbí àwọn orúkọ tó lè jọ ara wọn
Monífá
Meaning: I have Ifá.
Moníjésù
Meaning: I have Jesus.
Moníláárí
Meaning: I have significance.
Monílọ́lá
Meaning: I have (plenty/part) in wealth
Monínínúọlá
Meaning: I have my portion in nobility.
Monínúadé
Meaning: I have the mind/heart of a crown or royalty.
Monínúọlá
Meaning: I am filled with wealth.
Moníolúwa
Meaning: I have God.
Monísádé
Meaning: I have added to my crowns.
Monísimisínúọláolúwa
Meaning: I have rest in God's wealth/benefit.
Monísọ́lá
Meaning: I have had my honor added to.