Moborínínúọlá

Sísọ síta



Ìtumọọ Moborínínúọlá

I conquer in wealth.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

mo-borí-nínú-ọlá



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

mo - I
borí - conquer
nínú - inside of
ọlá - wealth


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Borí

Moborí