Méṣèrú

Sísọ síta



Ìtumọọ Méṣèrú

I don't make deceit.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

mé-ṣe-èrú



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

- I did not
ṣe - make, create (something good), do
èrú - trickery, dishonesty


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
YAGBA