Máfimíṣebi

Sísọ síta



Ìtumọọ Máfimíṣebi

Don't use me to do evil.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

má-fi-mí-ṣe-ibi



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

- do not
fi - use, put
- me
ṣe - make, create, do
ibi - evil


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
ILAJE