Págà! A kò rí oun tó jọ "Lẹ́gbẹ́"
Ǹjẹ́ o fẹ́ràn láti fi orúkọ kún àwọn orúkọ wa?
Jọ̀ọ́ lọ sí abala ibi tí a ti ń forúkọ sílẹ̀.Wò níbí àwọn orúkọ tó lè jọ ara wọn
Adáralẹ́gbẹ́
Meaning: One who is beautiful among company.
Alègbẹjọ́
Meaning: 'From Kogi'
Alẹ́gbẹ́lẹ́yẹ̀
Meaning: 1. Someone who has class and honour. 2. Whoever exists in a team has honour.
Amọ́lẹ́gbẹ́
Meaning: One pure in company.
Ẹlẹ́gbẹ́
Meaning: 1. A member of the Ẹgbẹ́ spiritual society; A worshipper of the Ẹgbẹ́ spirit. 2. One who is a member of a group, club, or society.
Elégbèdé
Meaning: The supporter has come.
Ẹlẹ́gbẹ́lẹ́yẹ
Meaning: Having the support of another is honourable. A person gains honour when he/she is accepted as kin(or peer).
Fálẹ́gbẹ́
Meaning: Ifá has no equal.
Ògúnlègbè
Meaning: Ògún is companionship.
Ilégbìjà
Meaning: The home avenged (us). See: Ilégbèjà