Págà! A kò rí oun tó jọ Lèrè
Ǹjẹ́ o fẹ́ràn láti fi orúkọ kún àwọn orúkọ wa?
Jọ̀ọ́ lọ sí abala ibi tí a ti ń forúkọ sílẹ̀.
Wò níbí àwọn orúkọ tó lè jọ ara wọn
Adélérè
Brief Meaning: The crown has rewards.
Akínsùnlérẹ̀
Brief Meaning: The valiant one slept in his house.
Akínwọlérẹ̀
Brief Meaning: Valor enters its house. The valiant one enters into his domain.
Akínwàlérè
Brief Meaning: Bravery exists as a reward.
Akéwúlérè
Brief Meaning: One who becomes successful by the business of Quran recitals.
Akínrelérẹ̀
Brief Meaning: The valiant one has gone to his home.
Ayélérè
Brief Meaning: Living in the world is profitable.
Ifálérè
Brief Meaning: Ifá (worship) has gains.
Olúwatúlérè
Brief Meaning: God still has/gives rewards.
Owómilérè
Brief Meaning: My money has reward.
Oyèlérè
Brief Meaning: Being titled (or having an important figure of the society) has merits.
Ògúnfúnmiléréṣe
Brief Meaning: Ògún gave me something to play with.
Súrùlérè
Brief Meaning: Patience has rewards.
Ìyàọmọlérè
Brief Meaning: Suffering for one's children has a reward.
Ṣelére
Brief Meaning: One who is born to set the house/family aright.
Ọlálérè
Brief Meaning: Wealth has rewards.
Ọmọlèrè
Brief Meaning: A child is one's reward.