Págà! A kò rí oun tó jọ Ladé
Ǹjẹ́ o fẹ́ràn láti fi orúkọ kún àwọn orúkọ wa? Jọ̀ọ́ lọ sí abala ibi tí a ti ń forúkọ sílẹ̀.

Wò níbí àwọn orúkọ tó lè jọ ara wọn


Láderin

Brief Meaning: Wealth becomes enormous.


Ládéga

Brief Meaning: The royal one is prominent.


Ládélé

Brief Meaning: A short form of "Ọládélé": Wealth/nobility has arrived at home.


Ládéníkà

Brief Meaning: Shortened form of Aládéníkà, the crowned one is not evil.