Págà! A kò rí oun tó jọ "Kọ̀yà"

Ǹjẹ́ o fẹ́ràn láti fi orúkọ kún àwọn orúkọ wa?

Jọ̀ọ́ lọ sí abala ibi tí a ti ń forúkọ sílẹ̀.

Wò níbí àwọn orúkọ tó lè jọ ara wọn

Adémókoyá

Meaning: Royalty helps improve (our) culture of farming.

Adékọyà

Meaning: The crown rejects suffering (on our behalf). Royalty defended us (from suffering).

Akọ̀yà

Meaning: One who rejects suffering.

Àgbẹ́kọ̀yà

Meaning: Farmer resists suffering.

Fákọ̀yà

Meaning: Ifá rejected suffering.

Mofikọ̀yà

Meaning: I reject suffering with this.

Odùkọ̀yà

Meaning: Odu (ifa) rejected suffering (on my behalf).

Olúkọ̀yà

Meaning: The prominent one rejected suffering.

Onàkọyà

Meaning: Ornaments have rejected suffering.

Shókọ̀yà

Meaning: The fertility god rejected suffering.

Shẹ̀nkọ̀yà

Meaning: Ùṣẹ̀n rejected (our) suffering.

Òbíkọ̀yà

Meaning: Parents have rejected suffering.

Ògúnkọ̀yà

Meaning: Ògún has rejected (our) suffering

Ọ̀shúnkọ̀yà

Meaning: Ọ̀ṣun rejects/rejected suffering.

Ọ̀ṣúnkọ̀yà

Meaning: Osun has rejected suffering.

Ṣókọ̀yà

Meaning: The sorcerer rejected suffering (for me).

Ṣẹ̀nkọ̀yà

Meaning: Ùṣẹ̀n rejects suffering.

Ẹfúnkọ̀yà

Meaning: Purity fought suffering (for me).

Ọbákọ̀yà

Meaning: The king rejected suffering. Ọbalúayé rejected suffering.

Ọkọ́ya

Meaning: The hoe broke.

Ọlọ́runkọ̀yà

Meaning: God rejected suffering.

Ọrẹ̀kọ̀yà

Meaning: The Ọrẹ̀ deity rejected (our) suffering.

Ọ̀rúnkọ̀yà

Meaning: Heaven rejects suffering (on our behalf).

Ọṣìkọ̀yà

Meaning: The king (who) defends his subjects from suffering.

Adékìyà

Meaning: A variant of Adékọ̀yà, the crown rejects suffering.

Ọkọ́ṣẹ́

Meaning: The hoe broke.

Browse Dictionary
a b d e f g gb h i j k l m n o p r s t u w y

Can't find what you are looking for? Contact Us.

Stay Updated

Get exclusive news, freebies, and lexicographer updates delivered to your inbox.

Yorùbá Keyboard

Write properly in Yorùbá with appropriate tone marks using our custom software for Mac & Windows.

Join the Community

Follow us on social media or volunteer to help us preserve the language.