Págà! A kò rí oun tó jọ Kọ̀ya
Ǹjẹ́ o fẹ́ràn láti fi orúkọ kún àwọn orúkọ wa?
Jọ̀ọ́ lọ sí abala ibi tí a ti ń forúkọ sílẹ̀.
Wò níbí àwọn orúkọ tó lè jọ ara wọn
Adémókoyá
Brief Meaning: Royalty helps improve (our) culture of farming.
Adékọyà
Brief Meaning: The crown rejects suffering (on our behalf). Royalty defended us (from suffering).
Akọ̀yà
Brief Meaning: One who rejects suffering.
Àgbẹ́kọ̀yà
Brief Meaning: Farmer resists suffering.
Fákọ̀yà
Brief Meaning: Ifá rejected suffering.
Mofikọ̀yà
Brief Meaning: I reject suffering with this.
Odùkọ̀yà
Brief Meaning: Odu (ifa) rejected suffering (on my behalf).
Olúkọ̀yà
Brief Meaning: The prominent one rejected suffering.
Onàkọyà
Brief Meaning: Ornaments have rejected suffering.
Shókọ̀yà
Brief Meaning: The fertility god rejected suffering.
Shẹ̀nkọ̀yà
Brief Meaning: Ùṣẹ̀n rejected (our) suffering.
Òbíkọ̀yà
Brief Meaning: Parents have rejected suffering.
Ògúnkọ̀yà
Brief Meaning: Ògún has rejected (our) suffering
Ọ̀shúnkọ̀yà
Brief Meaning: Ọ̀ṣun rejects/rejected suffering.
Ọ̀ṣúnkọ̀yà
Brief Meaning: Osun has rejected suffering.
Ṣókọ̀yà
Brief Meaning: The sorcerer rejected suffering (for me).
Ṣẹ̀nkọ̀yà
Brief Meaning: Ùṣẹ̀n rejects suffering.
Ẹfúnkọ̀yà
Brief Meaning: Purity fought suffering (for me).
Ọbákọ̀yà
Brief Meaning: The king rejected suffering. Ọbalúayé rejected suffering.
Ọkọ́ya
Brief Meaning: The hoe broke.
Ọlọ́runkọ̀yà
Brief Meaning: God rejected suffering.
Ọrẹ̀kọ̀yà
Brief Meaning: The Ọrẹ̀ deity rejected (our) suffering.
Ọ̀rúnkọ̀yà
Brief Meaning: Heaven rejects suffering (on our behalf).
Ọṣìkọ̀yà
Brief Meaning: The king (who) defends his subjects from suffering.
Adékìyà
Brief Meaning: A variant of Adékọ̀yà, the crown rejects suffering.
Ọkọ́ṣẹ́
Brief Meaning: The hoe broke.