Págà! A kò rí oun tó jọ Kìítẹ́
Ǹjẹ́ o fẹ́ràn láti fi orúkọ kún àwọn orúkọ wa?
Jọ̀ọ́ lọ sí abala ibi tí a ti ń forúkọ sílẹ̀.
Wò níbí àwọn orúkọ tó lè jọ ara wọn
Adéolúwakìítẹ́
Brief Meaning: The Lord's crown can never be put to shame.
Ọmolúwakìítẹ́
Brief Meaning: God's child will not be put to shame.
Ẹniọlákìtẹ́
Brief Meaning: A successful person cannot be put to shame.