Kálẹ́yẹmíjòwúrọ̀lọ

Pronunciation



Meaning of Kálẹ́yẹmíjòwúrọ̀lọ

May my latter days be more favourable than early years.



Morphology

kí-alẹ́-yẹ-mí-ju...lọ-òwúrọ̀



Gloss

kí - may
alẹ́ - night
yẹ - to be deserved, to deserve, to be favourable for
mí - me
ju...lọ - more than
òwúrọ̀ - morning


Geolocation

Common in:
GENERAL