Págà! A kò rí oun tó jọ Kànmí
Ǹjẹ́ o fẹ́ràn láti fi orúkọ kún àwọn orúkọ wa?
Jọ̀ọ́ lọ sí abala ibi tí a ti ń forúkọ sílẹ̀.
Wò níbí àwọn orúkọ tó lè jọ ara wọn
Adékànmí
Brief Meaning: The crown is now my turn.
Adéfarakànmí
Brief Meaning: Royalty touched me.
Ayọ̀kánmí
Brief Meaning: It is my turn to celebrate. Joy touched me.
Ayọ̀súnkànmí
Brief Meaning: Joy has moved close to me.
Ànúolúwayíkànmí
Brief Meaning: God's mercy rotated to me.
Fárúkànmí
Brief Meaning: The benefit of worshipping Ifá has reached me. [verification needed]
Fọlákànmí
Brief Meaning: Touch me with wealth/nobility.
Ireolúwakànmí
Brief Meaning: The goodness of God has come to me.
Lásúnkànmí
Brief Meaning: Wealth/Nobility shifted towards me.
Olúwafiorekànmi
Brief Meaning: God touched me with goodness.
Olúwarọ́kànmi
Brief Meaning: God saw my heart.
Olúwáfadékànmí
Brief Meaning: God made it my turn to wear the crown.
Oyèkànmí
Brief Meaning: I'm the next in line to be a installed a chief/king.
Ògúnfọlákànmí
Brief Meaning: Ògún touches me with honour (gives me wealth).
Súnkànmí
Brief Meaning: Come near me. [A short form of Ọlásúnkànmí]
Ògúnkànmí
Brief Meaning: Ògún (Ògún's blessings, presence, etc) touched me.
Ọkànmíyọ̀
Brief Meaning: My heart rejoices.
Ọlákànmí
Brief Meaning: Wealth has reached me.
Ọlásúnkànmí
Brief Meaning: It's my turn to be wealthy.
Lásún
Brief Meaning: Wealth moves closer.
Ọlásúkàmí
Brief Meaning: Wealth draws near to me.