Kòsílátẹ

Sísọ síta



Ìtumọọ Kòsílátẹ

(The child) is no longer available (to be bought).



Àwọn àlàyé mìíràn

The child can no longer "be bought" in the market, as it is now in its true home.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

kòsí-ní-àtẹ



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

kòsí - there isn't
- at
àtẹ - platform (for selling)


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
EKO