Págà! A kò rí oun tó jọ "Gòkè"
Ǹjẹ́ o fẹ́ràn láti fi orúkọ kún àwọn orúkọ wa?
Jọ̀ọ́ lọ sí abala ibi tí a ti ń forúkọ sílẹ̀.Wò níbí àwọn orúkọ tó lè jọ ara wọn
Adégòkè
Meaning: The crown has ascended.
Ayọ̀gòkè
Meaning: Joy has climbed to the top.
Ọlágòkè
Meaning: Wealth ascended, increased.
Ọlámigòkè
Meaning: My honor has increased.
Ọyagòkè
Meaning: The goddess Ọya (or her devotee) ascends (into greatness).
Oyègòkè
Meaning: Honour has climbed upwards.