Págà! A kò rí oun tó jọ "Gbulé"
Ǹjẹ́ o fẹ́ràn láti fi orúkọ kún àwọn orúkọ wa?
Jọ̀ọ́ lọ sí abala ibi tí a ti ń forúkọ sílẹ̀.Wò níbí àwọn orúkọ tó lè jọ ara wọn
Adégbulé
Meaning: Royalty fills the house.
Akíngbulé
Meaning: Valor has taken (over) the house.
Aládégbulé
Meaning: The royal one fills the house.
Fágbulẹ̀
Meaning: Ifá has sprouted and expanded over the land.
Omígbulé
Meaning: (The spirit of) Water fills the house.
Adébúlé
Meaning: Royalty did not arrive at home.