Gbádégún
Sísọ síta
Ìtumọọ Gbádégún
Make the crown straight/proper.
Àwọn àlàyé mìíràn
See: Mádégún
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
gbé-adé-gún
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
gbé - carryadé - crown, royalty
gún - set, to align, to be good.
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
GENERAL