Fọlárẹwà

Sísọ síta



Ìtumọọ Fọlárẹwà

Buy beauty with honour.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

fi-ọlá-rà-ẹwà



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

fi - use
ọlá - wealth, success, nobility, honour
- buy
ẹwà - beauty


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL