Elúfidódò
Sísọ síta
Ìtumọọ Elúfidódò
Elú used this child to block the river. [verification needed]
Àwọn àlàyé mìíràn
See Ògúnfidódò, Ọ̀ráfidódò
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
elú-fi-dí-odò
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
elú - an ancient Ife chieftaincy title; a class of Ifẹ̀ chiefsfi - use, put
dí - to block
odò - river
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
IFE