Egúndínà

Sísọ síta



Ìtumọọ Egúndínà

The Egúngún spirit has blocked the path (of evil).



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

eégún-dí-ọ̀nà



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

eégún - Egúngún masquerade; Egúngún spirit
- to allow (jí, jẹ́)
ọ̀nà - road, lane, way, path


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
OYO



Irúurú

Eégúndínà

Dínà