Págà! A kò rí oun tó jọ Dọjà
Ǹjẹ́ o fẹ́ràn láti fi orúkọ kún àwọn orúkọ wa? Jọ̀ọ́ lọ sí abala ibi tí a ti ń forúkọ sílẹ̀.

Wò níbí àwọn orúkọ tó lè jọ ara wọn


Adédọjà

Brief Meaning: The crown becomes valuable.


Ìbídọjà

Brief Meaning: Birth became a market.


Ládọjà

Brief Meaning: See: Ọládọjà: "Honour has become (famous/widely beloved/boisterous) like the marketplace".


Ògúndọjà

Brief Meaning: See: Adédọjà, Ọládọjà, Ọ̀ṣúndọjà, etc


Ọládọjà

Brief Meaning: Honour has become the market. Honour has become (famous/widely beloved/boisterous) like the marketplace.


Ọ̀pádọja

Brief Meaning: The (child of) Ọpá deity has become renowned (like the marketplace).


Ọ̀ṣúndọjà

Brief Meaning: The goddess Ọ̀ṣun has become prosperous (like a marketplace).