Págà! A kò rí oun tó jọ Diméji
Ǹjẹ́ o fẹ́ràn láti fi orúkọ kún àwọn orúkọ wa?
Jọ̀ọ́ lọ sí abala ibi tí a ti ń forúkọ sílẹ̀.
Wò níbí àwọn orúkọ tó lè jọ ara wọn
Ayọ̀diméjì
Brief Meaning: Joy became two.
Ládiméjì
Brief Meaning: (Our) wealth becomes two.
Ọlamidiméjì
Brief Meaning: My wealth is doubled.
Ọládiméjì
Brief Meaning: Affluence has become doubled.
Ọmọ́diméjì
Brief Meaning: My children have become two.
Ládi
Brief Meaning: A shortened form of "Oladipúpọ" or "Ọládiméjì" or "Ládiípọ̀"
Ògúndèjì
Brief Meaning: (The children of) Ògún have doubled.
Ayọ̀dimẹ́ta
Brief Meaning: Joy becomes three.
Akíndèjì
Brief Meaning: We're now twice as brave as we used to be.