Págà! A kò rí oun tó jọ "Déyẹmí"
Ǹjẹ́ o fẹ́ràn láti fi orúkọ kún àwọn orúkọ wa?
Jọ̀ọ́ lọ sí abala ibi tí a ti ń forúkọ sílẹ̀.Wò níbí àwọn orúkọ tó lè jọ ara wọn
Adéyẹmí
Meaning: 1. The crown is befitting of me. 2. One who arrives to befit me.
Adéyẹ́misí
Meaning: The Crown honors me
Ọdẹ́yẹmí
Meaning: I'm worthy of being a hunter.
Oyèyẹmí
Meaning: Honour is deserving of me. Chieftaincy/Title/kingship befits me.
Èṣúyẹmí
Meaning: Esu (worship) fits me.
Àyányẹmí
Meaning: Being a drummer befits me.
Yẹmí
Meaning: I am honourable.