Págà! A kò rí oun tó jọ "Débọ́lá"
Ǹjẹ́ o fẹ́ràn láti fi orúkọ kún àwọn orúkọ wa?
Jọ̀ọ́ lọ sí abala ibi tí a ti ń forúkọ sílẹ̀.Wò níbí àwọn orúkọ tó lè jọ ara wọn
Adébọ́lá
Meaning: 1. Crown meets wealth. 2. We returned to meet wealth. 3. Royalty gave birth to wealth.
Adébọ́lájí
Meaning: The crown wakes up with honor.
Adébọ́lájọ
Meaning: Royalty is at one with nobility.
Modébọ́lá
Meaning: I arrived to meet wealth already there.
Modébọ́lánlé
Meaning: I arrived at home to meet wealth already there.
Ọdẹ́bọ́lá
Meaning: 1. The hunter gave birth to wealth. 2. The hunter met/match wealth.