Págà! A kò rí oun tó jọ Dàpọ̀
Ǹjẹ́ o fẹ́ràn láti fi orúkọ kún àwọn orúkọ wa?
Jọ̀ọ́ lọ sí abala ibi tí a ti ń forúkọ sílẹ̀.
Wò níbí àwọn orúkọ tó lè jọ ara wọn
Adédàpọ̀
Brief Meaning: 1. Two crowns have joined together. 2. Royalty has increased in number.
Iwíndàpọ̀
Brief Meaning: Forest spirits joined with us.
Ìbídàpọ
Brief Meaning: Similar births.
Ìfẹ́dàpọ̀
Brief Meaning: Love adds up.
Olúdàpọ̀
Brief Meaning: The prominent one has become one (with us).
Oyèdàpọ̀
Brief Meaning: Honour mixes up.
Oṣódàpọ̀
Brief Meaning: The union of a family of the fertility god.
Wíndàpọ̀
Brief Meaning: (Two) Forest fairies collide.
Ọ̀jẹ́dàpọ̀
Brief Meaning: The lineage of masquerades has been added and mixed together.
Ṣódàpọ̀
Brief Meaning: See: Oṣódàpọ̀
Ọládàpọ̀
Brief Meaning: Wealth has been added, mixed up.
Ọládàpọ̀móyè
Brief Meaning: Honor has become mixed with chieftaincy.
Aróbíodu
Brief Meaning: One that makes a sound like the "odu".