Bámikẹ́gbẹ́
Sísọ síta
Ìtumọọ Bámikẹ́gbẹ́
Help me take care of this Ẹgbẹ́ (worshipper).
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
bá-mi-kẹ́-ẹgbẹ́
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
bá - together withmi - me
kẹ́ - to pamper, care for
ẹgbẹ́ - company, society, peer; Ẹgbẹ́ spirit
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
ABEOKUTA