Págà! A kò rí oun tó jọ Àrà
Ǹjẹ́ o fẹ́ràn láti fi orúkọ kún àwọn orúkọ wa?
Jọ̀ọ́ lọ sí abala ibi tí a ti ń forúkọ sílẹ̀.
Wò níbí àwọn orúkọ tó lè jọ ara wọn
Aranse
Brief Meaning: [unknown]
Arábámbí
Brief Meaning: Family/kin joined to give birth to this.
Arádéyọ̀
Brief Meaning: We found royalty and rejoiced.
Arájùlù
Brief Meaning: Kin is greater than the town.
Arámìdé
Brief Meaning: 1. My company, kin, or relative, has come. (Arámìdé) 2. My wonder has come (Àràmídé)
Aránmọ̀látẹ̀
Brief Meaning: We've sent the child to (sell at) the market.
Aráolúwa
Brief Meaning: 1. The lord's kin (Aráolúwa) 2. The lord's wonder (Àràolúwa)
Aráoyè
Brief Meaning: The kin of nobility.
Arápájà
Brief Meaning: One with arms competent to fight.
Arápáregángan
Brief Meaning: One with arms competent enough to dance to the gángan drums.
Arárọ̀mí
Brief Meaning: I am relieved.
Aráwọlé
Brief Meaning: Kinfolk have entered.
Arálamọ̀
Brief Meaning: We only know kin.
Arálọlá
Brief Meaning: Family/kin is one's honor.